NUJ pè fún ìṣèwáádí ikú tó pa akọ̀ròyìn VON
Ẹgbẹ́ àwọn Akọ̀ròyìn ti Ikọ̀ ìpínlẹ̀ Zamfara (NUJ), ti pe àwọn òṣìṣẹ́ elétò ìdìbò láti ṣe ìwáádí tó dáńgáájíá sí ikú tó pa àgbà akọ̀ròyìn tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Voice of Nigeria (VON), Hamisu Danjigba.
Ninu…