NRC ní kòsí n tó jọ pé wọ́n jí ọkọ̀ ojú irin kó lọ ní Borno
Ilé-iṣẹ́ tí ń mójútó Ọkọ̀ ojú Irin ní Nàìjíríà, (NRC) ti kọ ìjábọ̀ tí ó sọ pé wọ́n fẹ́ jí àwọn ọkọ̀ ojú irin gbé ní Maiduguri, ìpínlẹ̀ Borno.
Ọgbẹni Fidet Okhiria, Alakoso Olùdarí ile-iṣẹ naa ni o sọ eyi ni…