Ọgá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Borno Pín Àwọn Ọlọ́pàá Káàkiri Ìpínlẹ̀ Náà
Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Borno ní ọjọ́ Ẹtì, sọ́ pé àwọn yóò pín ọlọ́pàá tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gbokun láti Kọlẹẹjì, ẹgbẹ̀rin àtí méjìdínlógún sì gbogbo ìjọba ìbílẹ̀ láti kún àwọn ẹṣọ ààbò fún ètò ìdìbò gbogbogbòò 2023.
Ẹ tun lè kà nípa: Ọlọ́pàá…