Nàìjíríà Ní Látí Ṣé Ayẹyẹ Ọdún Òmínírá Ní Ìwọ́nbá
Àkọwé Ìjọba àpapọ̀ SGF, Ọ̀gbẹ́ni George Akume sọ pé ayẹyẹ́ Ọjọ́ Omínírá kẹtàlélọ́gọ́ta 63rd tí Nàìjíríà tó nbọ̀ ní ọjọ́ kíní Oṣú Kẹ́wàá yòó jẹ́ ní ìwọ́nbá.
Sẹnetọ Akume tó tún jẹ́ alagá ìgbímọ̀ àwọn minisita lori ayẹyẹ ọjọ ominira…