Ilé-iṣé Ológun Fún Àwọn Ológun Kàn Ní Àgbéga Lẹ́nu Iṣẹ́
Ilé-ìgbìmọ̀ Ọmọ-ogun Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìgbéga àwon òṣìṣẹ́ àgbà kàn sí Major General àti Brigadier General lẹsẹsẹ.
Èyí jẹ́ yọ́ látí orí ìkànnì X agbẹnusọ Ọmọ-ogun, Brigadier General Onyema Nwachuckwu ní ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kejilelogun, Oṣù…