2027: Àpérò Àwọn Aṣòfin Tẹ́lẹ̀ Ti Ṣ’àtìlẹ́yìn Fún Ààrẹ Tinubu
Àpérò Àwọn Aṣòfin Tẹ́lẹ̀ Ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣetán láti ṣ'àtìlẹ́yìn fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu, gẹ́gẹ́ bí olùdíje wọn kan ṣoṣo fún ìdìbò ààrẹ ọdún 2027 ní Nàìjíríà.
Wọn kéde ìtẹ́wọ́gbà náà ní Àpérò Orílẹ̀-èdè ti àpérò náà, èyí…