Nàìjíríà ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ ìṣètò Àyájọ́ òmìnira ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlé-lọ́gọ́ta
Ìjọba Nàìjíríà ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ ìṣètò elénìyàn mẹ́ẹ̀dógún fún ayẹyẹ ọdún Àyájọ́ òmìnira ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlé-lọ́gọ́ta oriĺẹ̀-èdè.
Akọwe fun Ijọba apapọ (SGF), George Akume ṣalaye pe ayẹyẹ naa yoo fun wọn lanfaani…