ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ Lekan Orenuga Feb 10, 2026 Ìjọba Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àwọn òun pàtàkì nínú àdéhùn tí wọ́n tún ṣe pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Àwọn Ọ̀gá Ilé-ẹ̀kọ́ gíga (ASUU). Mínísítà fún Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Tunji Alausa, nínú ìkéde tí Olùdarí Ìròyìn, Boriowo Folashade, gbé jáde, sọ…