Mínísítà FCT fi ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ta àwọn olóyè ìpele kẹta lọ́rẹ
Mínísítà Nàìjíríà ti olú ìlú, FCT, Nyesom Wike ti fa ọkọ̀ ayọ́kélẹ́ le àwọn Olóyè ìpele kẹta mẹ́wàá lọ́wọ́ ní olú ìlú tí ó sì tún pinnu láti ṣe àtúnṣe lórí ìgbé ayé ìrọ̀rùn fún àwọn olóyè náà.…