Ìpínlẹ̀ Èkó Ṣétán Látí Tíi Àwọn Ilé Tí Kò Ní Àpótí Ìdàlẹ̀nù Tó Yẹ́
Àjọ tó ń ṣètò ẹ̀gbin ní ìpínlẹ̀ Èkó, LAWMA tí sọ pé àwọn yóò bèrè sí ní tíì àwọn ilé tí wọ́n kò ní àpótí ìdọ̀tí ní Lagos Island àtí Lagos Mainland, bẹ̀rẹ̀ làti ọjọ keje oṣù keje ọdún 2023.
Èyí ló wáyé ṣáájú Ìkìlọ tí wọ́n tí sí àwọn…