Làásìgbò Sudan : Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí ṣòfò nínú ìkọlù ọjà Khartoum
Ó kéré ju ẹ̀nìyàn márùndín-lógójì ti pàdánù ẹ̀mí wọn nígbà tí “ ẹ̀rọ abúgbàmù “ dún ní ọjà kan tí ó máa ń kún ní olú ìlú Sudan, aláànú ìtọ́jú.
Médecins Sans Frontières (MSF) ṣapejuwe rẹ bii “o…