Adó Ìwakùsà Bú, Ó Pà Ènìyàn Mẹ́ta Ní Orílẹ̀-èdè Kenya
Àwọn àwakùsà góòlù pàdánù ẹ̀mí ènìyàn mẹ́ta ní ìgbà tí adó ìwakùsà bú ní àpá ìwọ̀ òòrùn ní Orílẹ̀-èdè Kenya.
Ilé iṣẹ́ ìwakùsà góòlù tí Karebe (Kerebe gold mining company) sọ pé ògiri kan tí wọ́n mọ́ láti dènà Omí yalé ní agbègbè náà ní…