Ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Super Eagles, Justice Christopher di olóògbé
Agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tẹ́lẹ̀ rí, Justice Christopher di olóògbé,ẹni ogójì ọdún níí ṣe.
Andrew Randa, oṣiṣẹ oniroyin ti orilẹ-ede fun ikọ ọkunrin ti ko ju ogun ọdun lọ,lo kede iku Christopher ninu tiwiti rẹ kan ni Ọjọbọ.…