Ìpínlẹ̀ Ọyọ buwọ́lu yíyá àwọn olùkọ́ni ní owó fún ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọyọ ti buwọ́lu ìyọ̀ǹda owó yíyá láti fi ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ fún àwọn olùkọ́ni ilé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ jákèjádò gbogbo ikọ̀ ní ìpínlẹ̀.
Alakooso oludari igbimọ eto ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ipinlẹ Ọyọ…