Ìjọba Nàìjíríà : Ìpèsè iná yóò ṣe déédé
Ààrẹ Bọla Tinubu ti kéde pé ìjọba òun ti gbáradì láti mójútó ìpeniníjà tí kò jẹ́ kí ìpèsè iná ṣe déedé ní orílẹ̀ -èdè.
O ni ijọba oun yoo pese idahun si oriṣiriṣi ipeninija jakejado ikọ ina kaakiri, pẹlu itura…