Ìlòkulò òògùn: Ìjọba Kwara yóò túnbọ̀ fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú NDLEA
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara, Àríwá Àringbùngbùn Nàìjíríà, ti túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ láti fìdí àjọṣepọ̀ ààrin rẹ̀ àti ilé-iṣẹ́ tó ń ṣe òfin òògùn lórílẹ̀-èdè (NDLEA), rinlẹ̀ si láti mú orísiríṣi lílo òògùn…