Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Lórí síso Àwọn ilé-iṣẹ́ Ìjọba pọ̀
Ilé-̀ìgbìmọ̀ Aṣojú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìfílọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ pàjáwìrì kan láti ṣe ìwádìí Ìṣẹ́pọ̀ àwọn iṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Olori ile igbimọ aṣoju, Hon. Fẹmi…