Ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣàjọyọ̀ fún Nàìjíríà ní ọdún mẹ́tàlé-lọ́gọ́ta
Àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin ti ṣàjọyọ̀ fún Nàìjíríà bí ó ṣe sàmì ọdún mẹ́tàlé-lọ́gọ́ta òmìnira.
Aṣoju Julius Ihonbvere wa gbe Igbesẹ kan lẹyin Iṣami yii, o ni Naijiria ti la aimọye ipeninija kọja ti wọn si ni…