Covid-19:Àwọn ènìyàn tó ní ààrùn covid 19 di márùún-dì́n-lógójí lórìlẹ̀-èdè…
Ile-iṣẹ ti o n ṣe amojuto gbigbogun ti aarun ni orilẹ-ede Naijiria,NCDC,ti sope awọn ti oni aarun marun-din-logoji tuntun miran ti jẹ yọ nì ọjọ aiku .
Pẹlu nọmba tuntun yii,awọn to ti ni aarun covid jẹ ọgọrun kan ati ọgọta mẹrin o din…