Ẹ máa dábàá láti yọ ààrẹ Buhari nípò -Ilé- iṣẹ́ ààrẹ
Ile-iṣẹ aarẹ ti kilọ fun awọn eniyan ti wọn n sara wọn jọ lati da wahalaa silẹ lorilẹ ede Naijiria , ti wọn si tun n lu ilu , kó bẹ́, ko bẹ́ , lati aarẹ Muhammadu Buhari kuro nipo aarẹ.
ile isẹ aarẹ tun ṣalaye itaniji ti o wa lati ẹka…