Ilé iṣẹ́ ààrẹ ṣe ayẹyẹ ọjọ́ọ́bí ọdún kẹtàlé-lọ́gọ́ta pẹ̀lú arábìnrin àkọ́kọ́…
Ilé iṣẹ́ ààrẹ ti ṣe ayẹyẹ ọjọ́ọ́bí ọdún kẹtàlé-lọ́gọ́ta pẹ̀lú arábìnrin àkọ́kọ́ Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Ìyáàfin Olurẹmi Tinubu, CON, OON.
Ninu alaye kan ti oludamọran pataki fun aarẹ lori eto ibaraẹnisọrọ ati ipolongo,…