Igbákejì Ààrẹ Shettima gbóríyìn fún ipa ìpínlẹ̀ Imo lórí ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè
Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti gbóríyìn fún ipa tí kòwọ́pọ̀ tí ì̀pí́nlẹ̀̀ Imo kó lórí ìdàgbàsókè òṣèlú, ọlọgbọ́n, àti ọrọ̀ ajé láti bíi ààdọ́ta ọdún sẹ́yìn, tí ó sì ń ṣàpèjúwe ìpínlẹ̀ náà bíi…