Ibùdó ìgbàni wọlé NYSC Borno ṣí padà lẹ́yìn ọdún mẹ́tàlá
Ibùdó ìgbàni wọlé Àgùnbánirọ̀, NYSC ti ìpínlẹ̀ Borno ti ṣí padà fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Àgùnbánirọ̀ tuntun, lẹ́yìn ọdún mẹ́tàlá látàrí láàsìgbò ọlọ́jọ́ gbọọrọ ní ìpínlẹ̀ náà.
Gomina ipinlẹ Borno, Ọjọgbọn…