Olórí Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba Nàìjíríà Rọ́ Àwọn Akọ̀wé Àgbà Túntún Látí Ṣiṣẹ́ Tọ́ Ètò Ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu
Olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (HoSF), Dókítà Folasade Yemi-Esan, tí gbá àwọn Akọ̀wé àgbà túntún níyànjú látí pá ọkàn wọ́n pọ̀ ṣiṣẹ́ tọ́ èròngbà ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu.
Ó sọ́ èyí làkókò tó ń ṣí dé ìpàdé ọlọọjọ́…