Hillary Clinton kó ààrùn còrónà
Akọ̀wé Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà nígbàkan rí, Hillary Clinton kéde ní ọjọ́ ajé, pé òhun ti kó ààrùn COVID-19 pẹ̀lú àmì àìsàn wérẹ́.
Eni ti o jẹ Ọmọ ọdun mẹrinle-laadọrin naa, ti o tun jẹ ẹni ti ẹgbẹ Democratic yan fun ipo…