Ìjọba Adamawa Gbé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ọmọdébìnrin Lárugẹ
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Adamawa ti bẹ̀rẹ̀ síí pín owó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogójì (N40,000) fún àwọn ọmọbìnrin ẹgbẹ̀rún mẹ́rinlèlógún (24,000) tí a fà láti àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mọ́kanlèlógún (21) ní ìpínlẹ̀ náà, lábẹ́ ètò Ìgbékalẹ̀ Owó Àfikún (CCT) tí…