Gómìnà Ọ̀ṣun pè fún àtúnṣe ẹ̀ka ààbò
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní gúsù iwọ̀-Oòrùn Nàìjíríà ti pè fún àtúnṣe ẹ̀ka ààbò Nàìjíríà láti jẹ́ kí wọ́n le ṣe iṣẹ́ tó múnádóko.
Gómìnà Adémọ́lá Adélékè pè ìpè yìí ní ọjọ́ Àìkú, níbi…