Gómìnà ìpínlẹ̀ Taraba: Ètò ẹ̀kọ́ jẹ wá lógún
Gómìnà Agbu Kefas ti Taraba, ti ṣe ìkéde pàjáwìrì lórí ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti gíga ní ìpínlẹ̀ náà.
Ó ṣe ìkéde yìí níbi ìbáraẹnisọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwọn akọ̀ròyìn ní ọjọ́ Àbámẹ́ta,ní Jalingo,…