Gómìnà ìpínlẹ̀ Sókótó ṣẹ̀dá ilé iṣẹ́ mẹ́fà tuntun
Lórí akitiyan rẹ̀ láti ṣe àtúntò àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ fún ṣíṣe iṣẹ́ tó múnádóko ní àwọn ilé-iṣẹ́ẹ gbogbogbòò ti ìpínlẹ̀ Sókótó,gómìnà Àmínù Wázírì Tambuwal,ti fọwọ́sí ṣíṣẹ̀dá àwọn ilé-iṣẹ́…