Gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe, Mínísítà ṣe ìfilọ́lẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe ilé-ìwé gíga fáfítì…
Gómìnà Muhammadu Yahaya ti ìpínlẹ̀ Gombe , Mínísítà fún lílọ bíbọ̀, Sẹ́nétọ̀ Sa’idu Alkali, àti Akọ̀wé aláṣẹ ti ìgbìmọ̀ tó ń mójútó Ìnáwó àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga, TETfund, Ọ̀gbẹ́ni Sunny Echono, ti ṣe ìfilọ́lẹ̀…