Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra ṣe ìrántí ikú àwọn akọni
Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, gúsù iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Charles Soludo, CFR ṣe ìrántí ikú àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà tí wọ́n fi ẹ̀mí wọn lélẹ̀ fún orílẹ̀-èdè.Ó gbóríyìn fún ọmọ ogun…