Nàìjíríà Tí Wà Ní Ipò Kẹrìndínlọ́gbọ̀n Nínú Àkàbà ìdíje FIFA Tuntun
Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà (Nigeria Super Eagles) ti wà ní ipò kẹrìndínlọ́gbọ̀n nínú àkàbà ìdíje FIFA tuntun, wọ́n sì ń gòkè sí ipò kẹta ní Áfíríkà.
Lágbàáyé, Spain ló dúró ní ipò àkọ́kọ́, lẹ́yìn náà ni Argentina àti Faransé, nígbà tí…