Wike Gbóríyìn Fún Ìdìbò Àlàáfíà Àti Ìwà Àwọn Olùdìbò
Mínísítà fún Agbègbè Olú-ìlú Nàìjíríà (FCT), Nyesom Wike, ti ṣàpèjúwe ìdìbò tí agbègbè Olú-ìlú Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí “àlàáfíà” ó sì gbóríyìn fún àwọn olùdìbò fún ìwà àlàáfíà.
Mínísítà náà gbóríyìn fún wọn lẹ́yìn tó ṣe àkíyèsí ìdìbò náà…