Bournemouth Yá Arsenal L’ẹnu Nígbàtí Aston Villa Ń Tẹ̀síwájú Lórí Tábìlì ‘EPL’
Bournemouth bóri Arsenal fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú ìdíje ilẹ́ Gẹ̀ẹ́sì 'English Premier League' ní Ọjọ́ Sátidé (Àbámẹ́ta), àti pé ìkọ náa túnramú ní ìdàkejì ìfẹ́sẹwọ́nsẹ́ ná èyí tó yá àwọn ènìyàn l'ẹ́nu bí wọ́n ṣé bóri pẹ̀lú ayo méjì sí ẹyọ kan…