Iyanṣẹlodi: Ẹgbẹ́ gbóríyìn fún ìjọba Nàìjíríà, ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ lórí ìpinnu
Àjọ àpapọ̀ àwọn agbanisísẹ́ ní Nàìjíríà, NECA, ti gbóríyìn fún ìjọba Nàìjíríà àti ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ lórí ìpinnu láti yẹ ìyanṣẹ́lódì tí kò lásìkò ní orílẹ̀-èdè.
Adari gbogbo NECA, Ọgbẹni Smatt Oyerinde…