Ẹ jẹ́ ká máa ní ìgbàgbọ́ nínú ìjọba
Wọ́n ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti máa nígbàgbọ́ àti láti gbé ìjọba ní gbogbo ìpele nígbùnwọ́ láti jẹ́ kí àwọn tó wà nípò adarí le ṣiṣẹ́ wọn bótitọ́ àti bó ṣe yẹ.
Mínísítà fún ọkọ̀ òfurufú tẹ́lẹ̀ rí,…