Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Dr Olubunmi Tunji-ojo

Ìjọba Nàìjíríà Kéde Ọjọ́ Kínní Oṣù Karùn-ún, Ọdún Yìí Fún Ìsinmi Àwọn Òṣìṣẹ́

Ìjọba Nàìjíríà tí kéde Ọjọ́bọ̀, ọjọ́ kínní oṣù kàrún, ọdún 2025 gẹ́gẹ́bí ọjọ́ ìsinmi fún gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ jákèjádò Orílẹ̀-èdè látí samisi Ayẹyẹ Ọjọ́ Àwọn òṣìṣẹ́ tí ọdún yìí. ‎ ‎ Mínísítà fún ètò abẹ́lé, Dókítà Olubunmi Tunji-Ojo, tó…

Ní Ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹta, Nàìjíríà Ṣèlérí Láti Mú Ìrọ̀rùn Bá Ọnà Látí Gbá Ìwé Ìrìnàjò Ní Kíkún

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí kéde ọjọ́ kínní Oṣù kẹta ọdún yìí gẹ́gẹ́ bí ìbẹrẹ ọjọ́ tí ìwé ìrìnnà yóò dí tí orí ayélujára pátápátá l'ójúnà látí mú ìrọ̀rùn àti ààbò bá àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ‎ ‎ Mínísítà fún intiriọ, Dókítà…
button