Covid-19:Ènìyàn mọ́kàndín-láàdọ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid
Ilé-iṣẹ́ tó nmójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NCDC ti mudánilójú pé àwọn ènìyàn mọ́kàndín-láàdọ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid.
Apapọ awọn to ti ni aarun naa lọwọlọwọ bayii jẹ…