COAS rọ àwọn ọmọ ogun láti má jáfara ní ìgbà ewu
Ọ̀gá àgbà fún àwọn Ọmọ -ogun, ajagun Faruk Yahaya ti pe, àwọn ọkùnrin àti obìnrin ọmọ -ogun Nàìjíríà níjà láti tiraka láti ríi dájú pé wọ́n ṣe bí olùkọ́ṣẹ mọṣẹ́ àti láti máá jáfara lásìkò ìrókẹ̀kẹ̀ sí…