COAS gbóríyìn fún Àwọn ọmọ ogun Fún àìtúrásílẹ̀ àti ìfaradà wọn
Ọ̀gá àgbà fún àwọn ọmọ ogun, ajagun Faruk Yahaya (COAS), sọ pé òhun nírètí pẹ̀lú àìtúrasílẹ̀ àti ìgboyà àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè (NACA) àti ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ìdánilékọ̀ọ́ àwọn ologun, (NATRAC)…