Ìgbákejì Ààrẹ Naìjírìà Balẹ̀ Sí Orílẹ̀-èdè China
Ìgbákejì Ààrẹ Naìjírìà, Kashim Shettima tí balẹ̀ sí Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè China, Beijing láti ṣé ojú Ààrẹ Bola Tinubu níbí ìpàdé tí yóò wáyé láti ọjọ́ kẹ́rindìnlógun (16th-18th) sí ọjọ́ kejidinlogun tí wọ́n pé àkọlé rẹ̀ ní 'High-quality Belt…