Boris Johnson Fí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin UK Sílẹ̀
Àdári Ìjọba tẹ́lẹ̀ rí tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì Boris Johnson f'ìwé mí ó ṣé mọ́ ránṣẹ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ní ọjọ́ Ẹtì látàrí ìwádìí àwọn aṣòfin lórí rẹ̀.
Johnson tí wà lábẹ́ ìwádìí àwọn aṣòfin nípasẹ̀ bóyá Ó dárí Ilé-ìgbìmọ̀…