Mínísítà Gbóríyìn Fún Àwọn Ẹṣọ Ghana Kán Fún Ìgbàlà Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Ogún-lugba-Dín-Kán
Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún ètò Ọrọ òkèèrè, Bianca Odumegwu-Ojukwu, tí gbóríyìn fún àwọn aláṣẹ orílẹ-èdè Ghana fún Ìgbàlà àwọn ọdọ Nàìjíríà Ogún-lugba-Dín-Kán (219) tí wọ́n gbé lọsí orílẹ-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà náà tí wọ́n sí fí ipá mú wọ́n…