Bendel Insurance Ṣe Ìyà Fún Enyimba Nínú Ìdíje NPFL
Bendel Insurance ṣe ìyà fún ikọ́ Enyimba FC 2-0 nínú ìpàdé wọn nínú ìdíje 'Nigeria Premier Football League NPFL', èyí tó ṣe ìwúrí àti ìrètí fún wọn lójúnà láti kópa nínú ìdíje CAF Champions League tàbí CAF Confederation Cup ní sáà…