Àwọn Òṣìṣẹ́ Òwò-Órí Orílẹ̀-èdè India Yábo Ilé-Ìṣẹ́ BBC
Àwọn Ilé-iṣẹ́ igbòhùnsáfẹ́fẹ́ BBC ní orílẹ̀-èdè India ní àwọn ẹ̀ṣọ́ òwò-òrí tí yábo fún ìwádìí.
Èyí ló ṣẹ̀lẹ̀ ní New Delhi àtí Mumbai tí wọ́n tí ṣọ̀ṣẹ́ lẹyìn ti “ilé iṣẹ́ ìròyìn kàn ṣé àfihàn ìtàn kàn ní orílẹ̀-èdè United Kingdom lórí…