Àwọn ọmọ ogun bẹ̀rẹ̀ Yíyan fún ìwà láláàfíà
Adarí àwọn ọmọ ogun Ikọ̀ karùnlé-lọ́gbọ́n, Ajagun Mohammed Tajudeen Aminu ti sọ pé ìwà lálàáfíà àwọn ọmọ ogun àti àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò jẹ́ ohun pàtàkì fún àṣeyege iṣẹ́ ológun.
Ajagun Aminu sọ eyi nigba ti o dari…