Àwọn Mínísítà fọwọ́sí ètò Àbojútó Àti àgbéyẹ̀wò ní orílẹ̀-èdè
Ìgbìmọ̀ Aláse àpapọ̀ ti fọwọ́sí ètò ìmúlò tuntun fún ìgbékalẹ̀ iṣé àbojútó àti àgbéyẹ̀wò ní Nìàjíríà.
Eto naa ni amọ si Eto Abojuto ati agbeyẹwo Orilẹ-ede.
Minisita fun eto iṣuna, inawo ati eto orilẹ-ede,…