Àwọn ènìyàn tó lé lẹ́gbẹ̀rún mẹ́jọ yóò péjọ fún IGF ní Japan
Àwọn ènìyàn tó lé lẹ́gbẹ̀rún mẹ́jọ jákèjádò àgbáyé ti ṣetán àti kórajọ fún Àpèjọ Ìṣàkóso Ayélujára (IGF), ẹlẹ́ẹ̀kejìdín-lógún ní Kyoto, orílẹ̀-èdè Japan, láti ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹwàá sí ọjọ́ kejìlá, 2023.…