Asia Game: Ó Dìn Díẹ̀ Ní Ìgbá Àwọn Éleré Ìdáráyá Tó Tí Yégé Ìdánwo – OCA
Ìgbímọ́ Olímpíìkì tí Asia sọ pé làárin Ọgọ́rùn-ún-lé-làádọ́ta sí ìgbá àwọn eleré ìdáráyá Asia ló tí yégé idánwo ẹjẹ́ wọ́n láìsí abájadé búrúkú títí dí isíyìn.
Nigbati on sọrọ nibi apejọ ti idanwo naa ni Hangzhou, China, sọ pe idanwo…