Arábìnrin àkọ́kọ́ Nàìjíríà gbàlejò àwọn ìyàwó ọ̀gá elétò ààbò
Iyawo aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Olurẹmi Tinubu sọ pe ki awọn ọmọ Naijiria maa jẹ ki bi igba ṣe ri bawọn ninu jẹ nitori pe ireti ṣi wa, ki wọn ma sọreti nu.
O n sọ eleyii ni ọjọ iṣẹgun nigba ti o n gbàlejò àwọn ìyàwó ọ̀gá elétò…